Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 35:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni titanna yio tanna; yio si yọ̀ ani pẹlu ayọ̀ ati orin: ogo Lebanoni li a o fi fun u, ẹwà Karmeli on Ṣaroni; nwọn o ri ogo Oluwa, ati ẹwà Ọlọrun wa.

Ka pipe ipin Isa 35

Wo Isa 35:2 ni o tọ