Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 35:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ẹni-iràpada Oluwa yio padà, nwọn o wá si Sioni ti awọn ti orin, ayọ̀ ainipẹkun yio si wà li ori wọn: nwọn o ri ayọ̀ ati inu didùn gbà, ikãnu on imí-ẹ̀dùn yio si fò lọ.

Ka pipe ipin Isa 35

Wo Isa 35:10 ni o tọ