Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 33:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti nrìn li ododo, ti o si nsọ̀rọ titọ́; ẹniti o gàn ère ininilara, ti o gbọ̀n ọwọ́ rẹ̀ kuro ni gbigbà abẹtẹlẹ, ti o di eti rẹ ni gbigbọ́ ti ẹ̀jẹ, ti o si di oju rẹ̀ ni riri ibi.

Ka pipe ipin Isa 33

Wo Isa 33:15 ni o tọ