Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 33:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

EGBÉ ni fun iwọ abanijẹ, ti a kò si bà ọ jẹ: ti o nhùwa arekereke, ti a kò si hùwa arekereke si ọ! nigbati iwọ o dẹkun ati banijẹ, a o bà ọ jẹ; ati nigbati iwọ bá fi opin si ihùwa arekereke, nwọn o hùwa arekereke si ọ.

Ka pipe ipin Isa 33

Wo Isa 33:1 ni o tọ