Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

On o si rọ̀ òjo si irugbin rẹ ti iwọ ti fọ́n si ilẹ: ati onjẹ ibísi ilẹ, yio li ọrá yio si pọ̀: li ọjọ na ni awọn ẹran rẹ yio ma jẹ̀ ni pápa oko nla.

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:23 ni o tọ