Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eti rẹ o si gbọ́ ọ̀rọ kan lẹhin rẹ, wipe, Eyiyi li ọ̀na, ẹ ma rin ninu rẹ̀, nigbati ẹnyin bá yi si apa ọtún, tabi nigbati ẹnyin bá yi si apa òsi.

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:21 ni o tọ