Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹnyin wipe, Bẹ̃kọ; nitori ẹṣin li a o fi sá; nitorina li ẹnyin o ṣe sá: ati pe, Awa o gùn eyi ti o lè sare; nitorina awọn ti yio lepa nyin yio lè sare.

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:16 ni o tọ