Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si fọ́ ọ bi fifọ́ ohun-èlo amọ̀ ti a fọ́ tútu; ti a kò dasi: tobẹ̃ ti a kì yio ri apãdi kan ninu ẹfọ́ rẹ̀ lati fi fọ̀n iná li oju ãro, tabi lati fi bù omi ninu ikũdu.

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:14 ni o tọ