Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA wipe, egbé ni fun awọn ọlọ̀tẹ ọmọ, ti nwọn gbà ìmọ, ṣugbọn kì iṣe ati ọdọ mi; ti nwọn si mulẹ, ṣugbọn kì iṣe nipa ẹmi mi, ki nwọn ba le fi ẹ̀ṣẹ kún ẹ̀ṣẹ:

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:1 ni o tọ