Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lọjọ na ni yio bura, wipe, Emi kì yio ṣe alatunṣe; nitori ni ile mi kò si onjẹ tabi aṣọ: máṣe fi emi ṣe alakoso awọn enia.

Ka pipe ipin Isa 3

Wo Isa 3:7 ni o tọ