Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 26:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa, ọwọ́ rẹ gbe soke, nwọn kì yio ri, ṣugbọn nwọn o ri, oju o si tì wọn nitori ilara wọn si awọn enia; nitõtọ, iná awọn ọta rẹ yio jẹ wọn run.

Ka pipe ipin Isa 26

Wo Isa 26:11 ni o tọ