Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 26:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LI ọjọ na li a o kọ orin yi ni ilẹ Juda; Awa ní ilu agbara; igbala li Ọlọrun yio yàn fun odi ati ãbo.

Ka pipe ipin Isa 26

Wo Isa 26:1 ni o tọ