Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 25:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

A o si sọ li ọjọ na pe, Wò o, Ọlọrun wa li eyi; awa ti duro de e, on o si gbà wa là: Oluwa li eyi: awa ti duro de e, awa o ma yọ̀, inu wa o si ma dùn ninu igbala rẹ̀.

Ka pipe ipin Isa 25

Wo Isa 25:9 ni o tọ