Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 20:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li ọba Assiria yio kó awọn ara Egipti ni igbèkun ati awọn ara Etiopia ni igbèkun, ọmọde ati arugbo, nihòho ati laibọ̀ bàta, ani ti awọn ti idí wọn nihòho, si itiju Egipti.

Ka pipe ipin Isa 20

Wo Isa 20:4 ni o tọ