Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 2:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni iwọ ṣe kọ̀ awọn enia rẹ, ile Jakobu silẹ̀; nitoriti nwọn kún lati ìla ọ̀run wá, nwọn jẹ alafọ̀ṣẹ bi awọn ara Filistia, nwọn si nṣe inu didùn ninu awọn ọmọ alejò.

Ka pipe ipin Isa 2

Wo Isa 2:6 ni o tọ