Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 2:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ na, enia yio jù òriṣa fadakà rẹ̀, ati òriṣa wurà rẹ̀, ti nwọn ṣe olukuluku wọn lati ma bọ, si ekute ati si àdan,

Ka pipe ipin Isa 2

Wo Isa 2:20 ni o tọ