Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 15:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori odò Dimoni yio kún fun ẹ̀jẹ: nitori emi o fi ibi miran sori Dimoni, emi o mu kiniun wá sori ẹniti ó sálà kuro ni Moabu, ati lori awọn ti o kù ni ilẹ na.

Ka pipe ipin Isa 15

Wo Isa 15:9 ni o tọ