Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 12:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, Ọlọrun ni igbala mi; emi o gbẹkẹle, emi ki yio si bẹ̀ru: nitori Oluwa Jehofah li agbara mi ati orin mi; on pẹlu si di igbala mi.

Ka pipe ipin Isa 12

Wo Isa 12:2 ni o tọ