Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 1:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẽṣe ti a o fi lù nyin si i mọ? ẹnyin o ma ṣọ̀tẹ siwaju ati siwaju: gbogbo ori li o ṣaisàn, gbogbo ọkàn li o si dakú.

Ka pipe ipin Isa 1

Wo Isa 1:5 ni o tọ