O si jọba lori gbogbo awọn ọba lati odò (Euferate) titi de ilẹ awọn ara Filistia ati de àgbegbe Egipti.