Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 9:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBATI ayaba Ṣeba gbọ́ òkiki Solomoni, o wá lati fi àlọ dan Solomoni wò ni Jerusalemu, pẹlu ẹgbẹ́ nlanla, ati ibakasiẹ ti o ru turari, ati wura li ọ̀pọlọpọ ati okuta iyebiye; nigbati o si de ọdọ Solomoni, o ba a sọ ohun gbogbo ti o wà li ọkàn rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Kro 9

Wo 2. Kro 9:1 ni o tọ