Ninu awọn ọmọ wọn, ti a ṣẹkù silẹ lẹhin wọn ni ilẹ na, ti awọn ọmọ Israeli kò run kuro, awọn ni Solomoni bu iṣẹ-ìrú fun titi o fi di oni yi.