Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 8:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Huramu si fi ọkọ̀ ranṣẹ si i, nipa ọwọ awọn iranṣẹ rẹ̀, ati awọn iranṣẹ ti o moye okun; nwọn si ba awọn iranṣẹ Solomoni lọ si Ofiri, lati ibẹ ni nwọn mu ãdọta-le-ni-irinwo talenti wura wá, nwọn si mu wọn tọ̀ Solomoni ọba wá.

Ka pipe ipin 2. Kro 8

Wo 2. Kro 8:18 ni o tọ