Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 7:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni emi o fà wọn tu ti-gbongbo-ti-gbongbo kuro ni ilẹ ti emi ti fi fun wọn; ati ile yi, ti emi ti yà si mimọ́ fun orukọ mi, li emi o ta nù kuro niwaju mi, emi o si sọ ọ di owe, ati ọ̀rọ-ẹgan larin gbogbo orilẹ-ède.

Ka pipe ipin 2. Kro 7

Wo 2. Kro 7:20 ni o tọ