Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 7:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi awọn enia mi ti a npè orukọ mi mọ́, ba rẹ̀ ara wọn silẹ, ti nwọn ba si gbadura, ti nwọn ba si wá oju mi, ti nwọn ba si yipada kuro ninu ọ̀na buburu wọn; nigbana ni emi o gbọ́ lati ọrun wá, emi o si dari ẹ̀ṣẹ wọn jì, emi o si wò ilẹ wọn sàn.

Ka pipe ipin 2. Kro 7

Wo 2. Kro 7:14 ni o tọ