Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 6:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn, bi nwọn ba rò inu ara wọn wò, ni ilẹ nibiti a gbe kó wọn ni igbekun lọ, ti nwọn ba si yipada, ti nwọn ba si gbadura si ọ li oko ẹrú wọn, wipe, Awa ti dẹṣẹ, awa ti ṣìṣe, awa si ti ṣe buburu;

Ka pipe ipin 2. Kro 6

Wo 2. Kro 6:37 ni o tọ