Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 6:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ki o gbọ́ li ọrun, ki o si dari ẹ̀ṣẹ awọn iranṣẹ rẹ ji, ati ti Israeli enia rẹ, nigbati iwọ ba ti kọ́ wọn li ọ̀na rere na, ninu eyiti nwọn o ma rìn: ki o si rọ òjo si ilẹ rẹ, ti iwọ ti fi fun awọn enia rẹ ni ini.

Ka pipe ipin 2. Kro 6

Wo 2. Kro 6:27 ni o tọ