Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 5:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọpa rẹ̀ wọnni si gùn tobẹ̃, ti a fi ri ori awọn ọpa na lati ibi apoti-ẹri na niwaju ibi mimọ́-jùlọ na, ṣugbọn a kò ri wọn li ode. Nibẹ li o si wà titi di oni yi.

Ka pipe ipin 2. Kro 5

Wo 2. Kro 5:9 ni o tọ