Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 5:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Solomoni ọba, ati gbogbo ijọ enia Israeli ti o pejọ si ọdọ rẹ̀, wà niwaju apoti-ẹrí na, nwọn si fi agutan ati malu rubọ, ti a kò le kà, bẹ̃ni a kò le mọ̀ iye wọn fun ọ̀pọlọpọ.

Ka pipe ipin 2. Kro 5

Wo 2. Kro 5:6 ni o tọ