Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 5:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe bi ẹnipe ẹnikan, nigbati a gbọ́ ohùn awọn afunpè ati awọn akọrin, bi ohùn kan lati ma yìn, ati lati ma dupẹ fun Oluwa; nigbati nwọn si gbé ohùn wọn soke pẹlu ipè ati kimbali, ati ohun-elo orin, lati ma yìn Oluwa pe, O ṣeun; ãnu rẹ̀ si duro lailai: nigbana ni ile na kún fun awọsanmọ, ani ile Oluwa;

Ka pipe ipin 2. Kro 5

Wo 2. Kro 5:13 ni o tọ