Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 4:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O ṣe agbada mẹwa pẹlu, o si fi marun si apa ọtún, ati marun si apa òsi, lati wẹ̀ ninu wọn: iru nkan ti nwọn fi nrubọ sisun ni nwọn nwẹ̀ ninu wọn; ṣugbọn agbada na ni fun awọn alufa lati ma wẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Kro 4

Wo 2. Kro 4:6 ni o tọ