Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 36:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati iyokù iṣe Jehoiakimu ati awọn ohun-irira rẹ̀ ti o ti ṣe, ti a si ri ninu rẹ̀, kiyesi i, a kọ wọn sinu iwe awọn ọba Israeli ati Juda: Jehoiakini, ọmọ rẹ̀, si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Kro 36

Wo 2. Kro 36:8 ni o tọ