Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 36:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nwọn fi awọn onṣẹ Ọlọrun ṣe ẹlẹya, nwọn si kẹgan ọ̀rọ rẹ̀, nwọn si fi awọn woli rẹ̀ ṣẹsin, titi ibinu Oluwa fi ru si awọn enia rẹ̀, ti kò fi si atunṣe.

Ka pipe ipin 2. Kro 36

Wo 2. Kro 36:16 ni o tọ