Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 36:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu, gbogbo awọn olori awọn alufa ati awọn enia dẹṣẹ gidigidi bi gbogbo irira awọn orilẹ-ède, nwọn si sọ ile Oluwa di ẽri, ti on ti yà si mimọ́ ni Jerusalemu.

Ka pipe ipin 2. Kro 36

Wo 2. Kro 36:14 ni o tọ