Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 36:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe eyi ti o buru li oju Oluwa Ọlọrun rẹ̀, kò si rẹ̀ ara rẹ̀ silẹ niwaju Jeremiah, woli, ti o sọ̀rọ lati ẹnu Oluwa wá.

Ka pipe ipin 2. Kro 36

Wo 2. Kro 36:12 ni o tọ