Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 34:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si de ọdọ Hilkiah, olori alufa, nwọn fi owo na ti a mu wá sinu ile Ọlọrun le e lọwọ, ti awọn ọmọ Lefi, ti o ntọju ilẹkun, ti kójọ lati ọwọ Manasse ati Efraimu, ati lati ọdọ gbogbo awọn iyokù Israeli, ati lati gbogbo Juda ati Benjamini: nwọn si pada si Jerusalemu.

Ka pipe ipin 2. Kro 34

Wo 2. Kro 34:9 ni o tọ