Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 34:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, emi o kó ọ jọ sọdọ awọn baba rẹ, a o si kó ọ jọ si isa-okú rẹ li alafia, bẹ̃ni oju rẹ kì yio ri gbogbo ibi ti emi o mu wá si ihinyi, ati sori awọn ti ngbe ibẹ. Bẹ̃ni nwọn mu èsi pada fun ọba wá.

Ka pipe ipin 2. Kro 34

Wo 2. Kro 34:28 ni o tọ