Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 34:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Ṣafani, akọwe, wi fun ọba pe, Hilkiah alufa, fun mi ni iwe kan. Ṣafani si kà a niwaju ọba.

Ka pipe ipin 2. Kro 34

Wo 2. Kro 34:18 ni o tọ