Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 34:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si mu owo na ti a mu wá sinu ile Oluwa jade wá, Hilkiah alufa, ri iwe ofin Oluwa ti a ti ọwọ Mose kọ.

Ka pipe ipin 2. Kro 34

Wo 2. Kro 34:14 ni o tọ