Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 33:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si gbé ere gbigbẹ kalẹ, ere ti o ti yá sinu ile Ọlọrun, niti eyiti Ọlọrun ti sọ fun Dafidi ati Solomoni, ọmọ rẹ̀, pe, Ninu ile yi, ati ni Jerusalemu ti emi ti yàn ninu gbogbo ẹ̀ya Israeli, li emi o fi orukọ mi si lailai:

Ka pipe ipin 2. Kro 33

Wo 2. Kro 33:7 ni o tọ