Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 33:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tun pẹpẹ Oluwa ṣe, o si rú ẹbọ alafia ati ẹbọ ọpẹ lori rẹ̀, o si paṣẹ fun Juda lati ma sìn Oluwa Ọlọrun Israeli.

Ka pipe ipin 2. Kro 33

Wo 2. Kro 33:16 ni o tọ