Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 32:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin eyi ni Sennakeribu, ọba Assiria, rán awọn iranṣẹ si Jerusalemu, (ṣugbọn on tikararẹ̀ dótì Lakiṣi ati gbogbo ogun rẹ̀ pẹlu rẹ̀) sọdọ Hesekiah, ọba Juda ati sọdọ gbogbo Juda ti o wà ni Jerusalemu wipe,

Ka pipe ipin 2. Kro 32

Wo 2. Kro 32:9 ni o tọ