Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 32:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hesekiah kanna yi li o dí ipa-omi ti o wà li òke Gihoni pẹlu, o si mu u wá isalẹ tara si iha iwọ-õrun ilu Dafidi. Hesekiah si ṣe rere ni gbogbo iṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Kro 32

Wo 2. Kro 32:30 ni o tọ