Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 32:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hesekiah si li ọrọ̀ li ọ̀pọlọpọ ati ọlá: o si ṣe ibi-iṣura fun ara rẹ̀ fun fadakà, ati fun wura, ati fun okuta iyebiye, ati fun turari ati fun apata, ati fun oniruru ohun-elo iyebiye.

Ka pipe ipin 2. Kro 32

Wo 2. Kro 32:27 ni o tọ