Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 32:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si rán Angeli kan, ẹniti o pa gbogbo awọn alagbara ogun, ati awọn aṣãju, ati awọn balogun ni ibudo ọba Assiria. Bẹ̃li o fi itiju pada si ilẹ on tikararẹ̀. Nigbati o si wá sinu ile oriṣa rẹ̀, awọn ti o ti inu ara rẹ̀ jade si fi idà pa a nibẹ.

Ka pipe ipin 2. Kro 32

Wo 2. Kro 32:21 ni o tọ