Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 32:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Enyin kò ha mọ̀ ohun ti emi ati awọn baba mi ti ṣe si gbogbo enia ilẹ miran? awọn oriṣa awọn orilẹ-ède ilẹ wọnni ha le gbà ilẹ wọn lọwọ mi rara?

Ka pipe ipin 2. Kro 32

Wo 2. Kro 32:13 ni o tọ