Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 31:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi aṣẹ na ti de ode, awọn ọmọ Israeli mu ọ̀pọlọpọ akọso ọkà ati ọti-waini ati ororo, ati oyin wá, ati ninu gbogbo ibisi oko; ati idamẹwa ohun gbogbo ni nwọn mu wá li ọ̀pọlọpọ.

Ka pipe ipin 2. Kro 31

Wo 2. Kro 31:5 ni o tọ