Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 31:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si fi ipin lati inu ini rẹ̀ sapakan fun ẹbọ sisun, fun ẹbọ sisun orowurọ ati alalẹ, ati ẹbọ sisun ọjọjọ isimi, ati fun oṣù titun, ati fun ajọ ti a yàn, bi a ti kọ ọ ninu ofin Oluwa.

Ka pipe ipin 2. Kro 31

Wo 2. Kro 31:3 ni o tọ