Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 31:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati fun awọn ọmọ Aaroni, awọn alufa, ti o wà li oko igberiko ilu wọn ni olukuluku ilu, awọn ọkunrin wà nibẹ, ti a pè li orukọ, lati ma fi fun gbogbo awọn ọkunrin ninu awọn alufa, ati fun gbogbo awọn ti a kà ni idile idile ninu awọn ọmọ Lefi.

Ka pipe ipin 2. Kro 31

Wo 2. Kro 31:19 ni o tọ