Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 30:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnyin ki o má si ṣe dabi awọn baba nyin, ati bi awọn arakunrin nyin, ti o dẹṣẹ si Oluwa, Ọlọrun awọn baba wọn, nitorina li o ṣe fi wọn fun idahoro, bi ẹnyin ti ri.

Ka pipe ipin 2. Kro 30

Wo 2. Kro 30:7 ni o tọ